Image for Olo´gbo` Olu`wo`sa`n Na´a` : Yoruba Edition of The Healer Cat

Olo´gbo` Olu`wo`sa`n Na´a` : Yoruba Edition of The Healer Cat (Softcover ed.)

See all formats and editions

Celesse, the healer cat, is a highly respected member of the neighborhood. As the mistress’s favorite cat, she spends lazy days in the warmth of the house.
One snowy night a mother hare rushes in, desperate for help. Reluctantly, the healer cat travels with her through a nighttime snowstorm and biting cold winds. In a dark forest, Celesse comes face-to-face with a scary surprise and is forced to gather her powers for the first time in a while.
---
Nítorí ẹ̀bùn rẹ̀, Celesse ológbò olùwòsàn jẹ́ ẹni tí a pọ́nlé gidi ní àdúgbò rẹ̀. Gẹ́gẹ́ bí ààyò fún ìyá àgbà, ó fẹ́ràn láti máa gbádùn àkókò tí kò bá níṣẹ́ nínú ilé rẹ̀.
Ṣùgbọ́n nígbà náà, ìyá ehoro kan wọlé, tí ó nbéèrè fún ìrànlọ́wọ́. Ìtẹnumọ́ rẹ̀ borí ìlọ́ra ti ológbò olùwòsàn, tí ó nmú u là yìnyín líle kọjá. Nínú igbó dúdú kan, Celesse dojúkọ ìyanu kan, èyí tí ó mú kí ó súnrakì.
Ní kété tí òru náà àti ìrìnàjò náà parí, oòrùn jáde, èyí tí ó fà ìlọ́wọ́wọ́ sórí àwọn ewéko àti sí ọkàn ológbò olùwòsàn.

Read More
Special order line: only available to educational & business accounts. Sign In
£8.72 Save 20.00%
RRP £10.90
Product Details
Wickwick Ltd
9523571249 / 9789523571242
Paperback / softback
21/07/2019
40 pages, Illustrations
203 x 254 mm, 127 grams
Children / Juvenile Learn More